Emma OhmaGod — Mowa Lati Josin - 9jasense.com

Emma OhmaGod — Mowa Lati Josin

Download Audio // Download Video
here i am to worship Yoruba version; mo wa lati j’osin Lyrics
(realgeeks.com.ng)
(intro)
OhMaGo
Mole Aye osokale ninu okunkun
si ojumi kinri o
ife tomu ki okan mi majubare
ireti fun ayemi pelu re
(chrorus)
Mowa lati J’osin
mowa lati teriba
mowa lati sowipe iwo lolorunmi
lapapo iwo lotosi
lapapoiwo leni ire
lapapo iyanu loje simi
(solo)
Oba ayeraye t’oungbe nibi giga
Ninu ogo kin rorun
ofi irele wa sinu aye ti o da
nitori ife odalaini
(chrorus)
Mowa lati J’osin
mowa lati teriba
mowa lati sowipe (realgeeks.com.ng) iwo lolorunmi
lapapo iwo lotosi
lapapo iwo leni ire
lapapo iyanu loje simi (repeat chorus)

bridge)
unkole mo iyetoje
latiwe ese mi lori agbelebu (3x)
(chrorus)
Mowa lati J’osin
mowa lati teriba
mowa lati sowipe iwo lolorunmi
lapapo iwo lotosi
lapapo iwo leni ire
lapapo iyanu loje simi (repeat chorus)

Olorun to da awon oke igbani
eyin mo fi ope mi fun
(realgeeks.com.ng)

Check  More Than Gold Judith Kanayo
Tags

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

2 × 2 =

Check Also
Close
Back to top button
Close
Close